Aisaya 8:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo bá pe Alufaa Uraya ati Sakaraya, ọmọ Jebẹrẹkaya, kí wọn wá ṣe ẹlẹ́rìí mi nítorí wọ́n jẹ́ olóòótọ́.

Aisaya 8

Aisaya 8:1-10