Aisaya 8:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, OLUWA sọ fún mi pé, “Mú ìwé kan tí ó fẹ̀, kí o kọ Maheriṣalali-haṣi-basi sí i lórí gàdàgbà gàdàgbà.”

Aisaya 8

Aisaya 8:1-9