Aisaya 8:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí ọwọ́ agbára ni OLUWA fi lé mi lára, nígbà tí ó ń sọ èyí fún mi. Ó sì ti kìlọ̀ fún mi pé kí n má bá àwọn eniyan wọnyi rìn, ó ní,

Aisaya 8

Aisaya 8:8-21