Aisaya 8:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ẹ gbìmọ̀ pọ̀ ìmọ̀ yín yóo di òfo.Ohun yòówù tí ẹ lè sọ, àpérò yín yóo di asán.Nítorí pé Ọlọrun wà pẹlu wa.

Aisaya 8

Aisaya 8:9-13