Aisaya 57:19-21 BIBELI MIMỌ (BM)

19. Alaafia ni, alaafia ni fún àwọn tí ó wà ní òkèèrè,ati àwọn tí ó wà nítòsí;n óo sì wò wọ́n sàn.

20. Ṣugbọn àwọn eniyan burúkú dàbí ríru omi òkun,nítorí òkun kò lè sinmi,omi rẹ̀ a sì máa rú pàǹtí ati ẹrẹ̀ sókè.

21. Kò sí alaafia fún àwọn eniyan burúkú.”Ọlọrun mi ló sọ bẹ́ẹ̀.

Aisaya 57