Aisaya 57:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn àwọn eniyan burúkú dàbí ríru omi òkun,nítorí òkun kò lè sinmi,omi rẹ̀ a sì máa rú pàǹtí ati ẹrẹ̀ sókè.

Aisaya 57

Aisaya 57:19-21