Aisaya 5:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ègbé ni fún àwọn tí wọ́n jí ní òwúrọ̀ kutukutu,láti máa wá ọtí líle kiri,tí wọ́n ń mu ún títí di ìrọ̀lẹ́,títí tí ọtí yóo fi máa pa wọ́n!

Aisaya 5

Aisaya 5:9-18