Aisaya 5:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Apẹ̀rẹ̀ èso àjàrà kan ni a óo rí ká ninu ọgbà àjàrà sarè mẹ́wàá.Kóńgò èso kan ni ẹni tí ó gbin kóńgò marun-un yóo rí ká.”

Aisaya 5

Aisaya 5:9-19