Aisaya 34:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ lọ wá inú ìwé OLUWA,kí ẹ ka ohun tí ó wà níbẹ̀.Kò sí ọ̀kan ninu àwọn wọnyi tí kò ní sí níbẹ̀,kò sí èyí tí kò ní ní ẹnìkejì.Nítorí OLUWA ni ó pàṣẹ bẹ́ẹ̀,ẹ̀mí rẹ̀ ni ó sì kó wọn jọ.

Aisaya 34

Aisaya 34:7-17