Aisaya 34:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Òwìwí yóo pa ìtẹ́ sibẹ, tí yóo máa yé sí.Yóo pamọ, yóo ràdọ̀ bo àwọn ọmọ rẹ̀,yóo sì máa tọ́jú wọn níbẹ̀.Àwọn àṣá yóo péjọ sibẹ,olukuluku wọn, pẹlu ekeji rẹ̀.

Aisaya 34

Aisaya 34:12-17