Aisaya 26:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọkàn mi ń ṣe àfẹ́rí rẹ lálẹ́,mo sì ń fi tọkàntọkàn wá ọnítorí nígbà tí ìlànà rẹ bá wà láyéni àwọn ọmọ aráyé yóo kọ́ òdodo.

Aisaya 26

Aisaya 26:1-10