Aisaya 26:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí a bá ṣàánú ẹni ibi,kò ní kọ́ láti ṣe rere.Yóo máa ṣe ibi ní ilẹ̀ àwọn olódodo,kò sì ní rí ọlá ńlá OLUWA.

Aisaya 26

Aisaya 26:8-14