O sọ àwọn ìlú di òkítì àlàpào sì ti pa àwọn ìlú olódi run.O wó odi gíga àwọn àjèjì, kúrò lẹ́yìn ìlú,ẹnikẹ́ni kò sì ní tún un kọ́ mọ́.