Aisaya 25:1 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA, ìwọ ni Ọlọrun mi.N óo gbé ọ ga:n óo yin orúkọ rẹ.Nítorí pé o ti ṣe àwọn nǹkan ìyanu,o ti ṣe àwọn ètò láti ìgbà àtijọ́,o mú wọn ṣẹ pẹlu òtítọ́.

Aisaya 25

Aisaya 25:1-9