Aisaya 24:10-12 BIBELI MIMỌ (BM)

10. Ìlú ìdàrúdàpọ̀ ti wó palẹ̀, ó ti dòfo,gbogbo ìlẹ̀kùn ilé ti tì, kò sì sí ẹni tí ó lè wọlé.

11. Ariwo ta lóde nítorí kò sí ọtí waini,oòrùn ayọ̀ ti wọ̀;ayọ̀ di àwátì ní ilẹ̀ náà.

12. Gbogbo ìlú ti di ahoro,wọ́n ti wó ẹnu ibodè ìlú wómúwómú.

Aisaya 24