Aisaya 2:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọn óo wọ inú pàlàpálá àpáta,ati inú ihò àwọn òkè gíga;nígbà tí wọn bá ń sá fún ibinu OLUWA,ati ògo ọlá ńlá rẹ̀,nígbà tí ó bá dìde láti mi ayé tìtì.

Aisaya 2

Aisaya 2:20-22