Aisaya 2:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ náà,àwọn eniyan óo kó àwọn ère fadaka wọn dànù,ati àwọn ère wúrà tí wọ́n fi ọwọ́ ara wọn ṣe, tí wọn tún ń bọ.Wọn yóo dà wọ́n fún àwọn èkúté ati àwọn àdán.

Aisaya 2

Aisaya 2:14-22