Aisaya 19:2 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo dá ìdàrúdàpọ̀ sílẹ̀ láàrin àwọn ará Ijipti,olukuluku yóo máa bá arakunrin rẹ̀ jà,àwọn aládùúgbò yóo máa bá ara wọn jà,ìlú kan yóo gbógun ti ìlú keji,ìjọba yóo máa dìde sí ara wọn.

Aisaya 19

Aisaya 19:1-4