Aisaya 19:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Àsọtẹ́lẹ̀ nípa Ijipti nìyí:OLUWA gun ìkùukùu lẹ́ṣin, ó ń yára bọ̀ wá sí Ijipti.Àwọn oriṣa Ijipti yóo máa gbọ̀n níwájú rẹ̀,ọkàn àwọn ará Ijipti yóo sì dàrú.

Aisaya 19

Aisaya 19:1-8