Aisaya 19:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọ̀jọ̀gbọ́n rẹ dà?Níbo ni wọ́n wà kí wọ́n sọ fún ọ,kí wọ́n sì fi ohun tí OLUWA àwọn ọmọ ogun pinnu láti ṣe sí Ijipti hàn ọ́.

Aisaya 19

Aisaya 19:2-13