Òmùgọ̀ ni àwọn olórí wọn ní Soani;ìmọ̀ràn wèrè sì ni àwọn ọ̀jọ̀gbọ́n ìgbìmọ̀ Farao ń fún eniyan.Báwo ni eniyan ṣe lè sọ fún Farao pé,“Ọmọ Ọlọ́gbọ́n eniyan ni mí,ọmọ àwọn ọba àtijọ́.”