Aisaya 17:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Tó bá di ìgbà náà, àwọn eniyan yóo bọ̀wọ̀ fún Ẹlẹ́dàá wọn, wọn yóo sì máa wo ojú Ẹni Mímọ́ Israẹli.

Aisaya 17

Aisaya 17:1-14