Aisaya 17:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Àṣàkù yóo kù níbẹ̀,bí ìgbà tí eniyan gbọn igi olifi,yóo ku meji tabi mẹta péré ní góńgó orí igi,tabi bíi mẹrin tabi marun-un lórí ẹ̀ka igi.”OLUWA Ọlọrun Israẹli ló sọ bẹ́ẹ̀.

Aisaya 17

Aisaya 17:1-14