Aisaya 16:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Wọ́n ti kó àgbò láti Sela, ní ọ̀nà aṣálẹ̀,wọ́n fi ranṣẹ sí aláṣẹ ilẹ̀ náà, ní òkè Sioni.

2. Àwọn ọmọbinrin Moabu dúró létí odò Anoni,wọ́n ń rìn síwá, sẹ́yìn,wọ́n ń lọ sókè, sódò,bí ọmọ ẹyẹ tí a lé kúrò ninu ìtẹ́.

Aisaya 16