Aisaya 16:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọbinrin Moabu dúró létí odò Anoni,wọ́n ń rìn síwá, sẹ́yìn,wọ́n ń lọ sókè, sódò,bí ọmọ ẹyẹ tí a lé kúrò ninu ìtẹ́.

Aisaya 16

Aisaya 16:1-11