Aisaya 11:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Òdodo ni yóo fi ṣe àmùrè ìgbàdí rẹ̀,yóo sì fi òtítọ́ ṣe àmùrè ìgbànú rẹ̀.

Aisaya 11

Aisaya 11:3-15