Aisaya 11:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn yóo fi òdodo ṣe ìdájọ́ àwọn talaka,yóo fi ẹ̀tọ́ gbèjà àwọn onírẹ̀lẹ̀,yóo fi ọ̀rọ̀ ẹnu rẹ̀ na ayé bíi pàṣán,yóo sì fi èémí ẹnu rẹ̀ pa àwọn oníṣẹ́ ibi.

Aisaya 11

Aisaya 11:1-14