Sekaráyà 4:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo sì tún dáhùn, mo sì sọ fún un pé, “Kí ni àwọn ẹ̀ka méjì igi wọ̀nyí jásí, tí ń tú òróró wúrà jáde nínú ara wọn láti ẹnu ọ̀pá oníhò wúrà méjì.”

Sekaráyà 4

Sekaráyà 4:4-14