Sekaráyà 4:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo sì béèrè, mo sì sọ fún un pé, “Kí ni àwọn igi ólífì méjì wọ̀nyí jásí, tí ó wà ní apá ọ̀tún fìtílà àti ní apá òsì rẹ̀?”

Sekaráyà 4

Sekaráyà 4:3-14