Sáàmù 89:51-52 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

51. Ẹ̀gàn tí àwọn ọ̀tá Rẹ gàn, Olúwa,tí wọn gan ipaṣẹ̀ Ẹni àmì òróró Rẹ.

52. Olùbùkún ní Olúwa títí láé.Àmín àti Àmín.

Sáàmù 89