Sáàmù 88:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ ti mú ọ̀rẹ́ àti olùfẹ́ mi kúrò lọ́dọ̀ mi;òkùnkùn sì jẹ́ ọ̀rẹ́ tímọ́tímọ́ mi.

Sáàmù 88

Sáàmù 88:10-18