Sáàmù 67:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọlọ́run yóò bùkún fún wa,àti gbogbo òpin ilẹ̀ ayé yóò sì máa bẹ̀rù Rẹ̀.

Sáàmù 67

Sáàmù 67:5-7