Sáàmù 67:5-7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

5. Kí àwọn ènìyàn kí ó yìn ọ́, Ọlọ́run;kí gbogbo ènìyàn kí ó yìn ọ́. Sela

6. Nígbà náà ní ilẹ̀ yóò mú ìkórè Rẹ̀ wá, Ọlọ́run,Ọlọ́run wa yóò bùkún fún wa.

7. Ọlọ́run yóò bùkún fún wa,àti gbogbo òpin ilẹ̀ ayé yóò sì máa bẹ̀rù Rẹ̀.

Sáàmù 67