Sáàmù 58:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jẹ́ kí wọn rí bí ìgbín tí Rẹ̀ dànù tí ó sì ṣègbébí ọmọ ti oṣu Rẹ̀ kò pé, kí wọn má ṣe rí òòrùn.

Sáàmù 58

Sáàmù 58:1-11