Sáàmù 58:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jẹ́ kí wọn parẹ́ bí omi tó ń ṣàn lọ;nígbà tí ó bá fa ọfà Rẹ̀, kí ọ̀kọ̀ wọn kí ó ṣẹ́.

Sáàmù 58

Sáàmù 58:1-9