Sáàmù 139:22-24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

22. Èmi korìíra wọn ní àkótán;èmi kà wọ́n sí ọ̀tá mi.

23. Ọlọ́run, wádíì mi, kí ó sì mọ ọkàn mí;dán mi wò, kí ó sì mọ ìrò inú mi

24. Kí ó sì wò ó bí ipa ọ̀nà búburúkan bá wà nínú mi kí ó sìfi ẹṣẹ̀ mi lé ọ̀nà àìnípẹ̀kun.

Sáàmù 139