Sáàmù 138:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa yóò ṣe ohun tí ń ṣe tèmi láṣepé; Olúwa, àánú Rẹ̀ dúró láéláé;Má ṣe kọ isẹ́ ọwọ́ ara Rẹ̀ sílẹ̀.

Sáàmù 138

Sáàmù 138:1-8