Sáàmù 119:174-176 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

174. Èmi wo ọ̀nà fún ìgbàlà Rẹ, Olúwa,àti òfin Rẹ jẹ́ dídùn inú mi.

175. Jẹ́ kí èmi wà láàyè ki èmi lè yìn ọ́,kí o sì jẹ́ kí òfin Rẹ mú mi dúró.

176. Èmí ti sìnà bí àgùntàn tí ósọnùú wá ìránṣẹ́ Rẹ,nítorí èmi kò gbàgbé àṣẹ Rẹ.

Sáàmù 119