Sáàmù 119:174 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi wo ọ̀nà fún ìgbàlà Rẹ, Olúwa,àti òfin Rẹ jẹ́ dídùn inú mi.

Sáàmù 119

Sáàmù 119:169-176