Sáàmù 119:173 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jẹ́ kí ọwọ́ Rẹ ṣetan láti rànmílọ́wọ́,nítorí èmi ti yan ẹ̀kọ́ Rẹ.

Sáàmù 119

Sáàmù 119:168-176