Róòmù 14:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ta ni ìwọ láti dá ọmọ ọ̀dọ̀ tí kì í se tìrẹ lẹ́jọ́? Lójú olúwa tirẹ̀ ni òun ni dúró, tàbí subú. Òun yóò sì dúró nítorí Ọlọ́run ní agbára láti mú kí òun dúró.

Róòmù 14

Róòmù 14:3-9