Róòmù 14:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ẹni tí ń jẹ ohun gbogbo má ṣe kẹ́gàn ẹni tí kò jẹ; kí ẹni tí kò sì jẹ ohun gbogbo kí ó má ṣe dá ẹni tí ń jẹ lẹ́bi: nítorí Ọlọ́run ti gbà á.

Róòmù 14

Róòmù 14:1-8