Róòmù 14:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èése nígbà náà tí ìwọ fi ń dá arakùnrin rẹ lẹ́jọ́? tàbì èése tí ìwọ sì ń fi ojú ẹ̀gàn wo arakùnrin rẹ? Nítorí olúkúlùkù wa ni yóò dúró níwájú ìtẹ́ ìdájọ́ Ọlọ́run.

Róòmù 14

Róòmù 14:2-16