Òwe 26:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí èédú ti rí sí ẹyin iná, igi fún iná,bẹ́ẹ̀ ni ènìyàn oníjà fún ìjà dídá sílẹ̀.

Òwe 26

Òwe 26:11-28