Oníwàásù 5:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo ti rí ohun tí ó burú gidigidi lábẹ́ oòrùnọrọ̀ tí a kó pamọ́ fún ìparun oní nǹkan.

Oníwàásù 5

Oníwàásù 5:5-16