Oníwàásù 5:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Oorun alágbàṣe a máa dùn,yálà ó jẹun kékeré ni tàbí ó jẹun púpọ̀,ṣùgbọ́n ọ̀pọ̀ ọ̀rọ̀ ọlọ́rọ̀kì í jẹ́ kí ó ṣùn rárá.

Oníwàásù 5

Oníwàásù 5:2-20