Oníwàásù 1:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ohun tí ó ti wà tẹ́lẹ̀ náà ni yóò sì máa wà, ohun tí a ti ṣe sẹ́yìnòun ni a ó tún máa ṣe padàkò sí ohun tuntun lábẹ́ oòrùn.

Oníwàásù 1

Oníwàásù 1:8-11