Oníwàásù 1:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ohun gbogbo ni ó ń mú àárẹ̀ wá,ju èyí tí ẹnu le è ṣọojú kò tí ì rí ìrírí tí ó tẹ́ẹ lọ́rùn,bẹ́ẹ̀ ni, etí kò tí ì kún fún gbígbọ́.

Oníwàásù 1

Oníwàásù 1:5-15