Onídájọ́ 8:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣébà àti Ṣálímúnà, àwọn ọba Mídíánì méjèèjì sá, ṣùgbọ́n Gídíónì lépa wọn ó sì mú wọn, ó run gbogbo ogun wọn.

Onídájọ́ 8

Onídájọ́ 8:4-19