Onídájọ́ 6:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo wí fún un yín pé, èmi ni Olúwa Ọlọ́run yín: ẹ má ṣe sin àwọn òrìṣà àwọn ará Ámórì, ní ilẹ̀ ẹni tí ẹ̀yin ń gbé. Ṣùgbọ́n ẹ̀yin kò gbọ́ràn sí ohun tí mo sọ.”

Onídájọ́ 6

Onídájọ́ 6:8-11